EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE Apejuwe iro konsonanti Iro konsonanti ni iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi gbe won jade. A le pin iro konsonanti si ona wonyi; 1. Ibi isenupe 2. Ona isenupe 3. Ipo alafo tan-an-na Ibi isenupe: Eyi ni ogangan ibi ti a ti pe iro konsonanti ni enu. O le je afipe asunsi tabi akanmole. Afeji-ete-pe. ( B, m) Ete oke ati ate isale pade-apipe akanmole ati asunsi pade Afeyin Fetepe ( f ) Ete isale ati eyin oke pade afipe asunsi ati akanmole pade Aferigipe, (T d,s,n,r,l) Iwaju ahon sun lo ba erigi oke . afipe asunsi ati afipe akanmole Afaja ferigipe. ( J,s,) Iwaju ahon sun kan erigi ati aarin aja enu. afipe ati afipe Afajape (Y) Aarin ahon sun lo ba aja enu. afipe asunsi ati akanmole Afafasepe (K, g) Eyin ahon sun lo kan afase .afipe asunsi ati akanmole Afafasefetepe (Kp, gb,w) Ete mejeji papo pelu eyin ahon kan afase . afipe asunsi ati afipe akanmole Afitan - an-na – pe (H) Inu alafo tan-an na ni a fi pe e Ona isenupe: Eyi toke si ir
AKOLE ISE: ATUYEWO AWON EYA ARA - IFO (EYA ARA ISORO) Eya ara ifo ni eya ara ti a maa n lo fun gbigbe iro ifo jade A le pin eya ara ifo si isori meji, awon ni; Eya ara ifo ti a le fi oju ri: apeere: ete oke, ete isale, eyin oke, e yin isale, evigi, aja enu, iwaju a lo n, aarin lion, eyin ahon, afase, ita gongongo, olele, aja-enu, kaa imu Eya ara ifo ti a ko le fi oju ri: Apeere; Edo-foro, komookun, eka-komookun, tan-an-na, inu gogongo, kaa ofun. AWON EYA ARA TI A FI N PE IRO EDE AFIPE: Afipe ni gbogbo eya ara ifo ti won kopa ninu pipe iro ede jede. A le pin awon afipe wonyi si meji; awon nii APIPE ASUNSI: Eyi ni afipe ti o le gbera nigba ti a aba n pe iro won maa n sun soke sodo ti aban soro. Apeere; Afipe asunsi ni, Ete Isale, Eju isale, iwaju alion, aarin alion, eyin ahon, olele. AFIPE AKANMOLE: Eyi ni awon afipe ti ko le gbara soke sugbon ti won maa n duro gbari bi a ba n pe iro jade. Apeere afipe akonmole ni, ete oke, aja-enu, afase, iganna ofun, eyin oke, erigi, olele. Ipo ti ah