Skip to main content

AROKO PIPA

 



AROKO PIPA

Aroko pipa je ona ti awon baba nla wa fi n ba ara won soro asiri lai fie nu so. Arin ni won fi n ranse si eniyan ti yoo si mo itumo re. Aroko kiko dabi leta ni aye ode – onu .

ORISIIRISII AROKO AYE ATIJO

1.      AALE – ni ami ti afile eru, esotabi eniyan lati fi kilo fun awon ole tabi eniyan ki o mase mu nnkan naa. Awon nikan aale ni wonyii – lkearahun igbin, Akisa aso, Aso pupa, Suku agbado, Erupe, okuta, oogun (Magun) thunder-boat) Ale paale si ara igi osan ati eso miran, oju ona, enu ibode ilu, ori aatan, inu oko abbl.

2.     TESOO – Ni aale t a fi si ara omo ikose tabi omo ile – ire ki o bal aye kawe tabi kose re ja.

3.     AAGA – Ni ami ti a ta mo ara igi meji ti a ri mole lati fi kilo funn eniyan lati sa fun ewu. Won meta ri tanaage si ori aatan, orille tabi oko ohun ti won n lo ni mariwo, ope, aso pupa, eni tabi okun agba ti a ta mo igi.

4.     ITUFU – Ni awon nukan to le mu ina wa ti a gbe si eyinkille eniyan jau lati fi kilo fun ini eni bee ko won bo wa jo ile re. Awon ohu itufu ni – Atupa isana, oguso, Epo oyinbo, iha, petin gaasi.

5.     ASEWELEWE—Ni ji ja ewe tutu sile ni ikorita bi amu lati fi so fun awon ti won dijo n lo si lbi kan pe awon ti ko ja si iwoju.

AMIIPAROKO

ITUMO

Owo eyo

Eni naa ti di eni itanu

Ikarahun igbin

ife nini, okan re ri fami

Iye

Wa kiakia, ija ti pari lotifo lo bi eye

Iye Ayekooto

Sora lati so otito

Aidan

Wa so gbese re ni kiakia

Ajoku Owu

Iku tabi ewu wa nitosi

Awoehoro

Sa jina rere, ewuwa nitosi

Awo oju ilu

Oro ti kuro ni asiri gbogbo aye ti mo

Awe obi

Oro naa ko gbodo suo

Kaun kaun osun ati ose

iyawore ti bi omo tuntun

obi

Gbo temi

Igbale lowo

jade ni ile mi / le eni to mu aroko yii naa jade ni ile

Sigidi

Eni naa n sere été ofete

Suku Agbado

Ko ni ri aso bora tabi ihoho ni eni naa yooku si

 

 

 

AROKO AYE ODE ONI

1.      Ina monamona adari-oko

2.     Isoda elese

3.     Patako ajuwe ona

4.     Ibi ti o ni owu

5.     Leta kiko

Comments

Popular posts from this blog

AWON ORISA ILE YORUBA

ISORI EKO : AWON ORISA ILE YORUBA Awon Yoruba gba awon orisa bii asoju tabi iranse olodumare, alarina, lagata tabi alagbewi ni won je. Ero awon Yoruba ni pe olorun feran awon orisa wonyi.   Okanlenirinwo ni awon orisa ile Yoruba . lara won ni Obatala, Orunmila, Esu, Sango, Ogun ati bee bee lo   Obatala ni awon Yoruba pe ni ALAMORERE . Won gbagbo pe oun ni o mo gbogbo eya ara eniyan ki olodumare to mi emi iye si inu won Funfun   ni awon ohun elo obatala, lara won ni ileke funfun, aso funfun, bata funfun. Ounje ti o feran julo ni obe ate ( obe ti ko ni iyo ), igbin ati iyan. Omi ajipon ni obatala maa n mu. Ko feran iwa aito bi iro pipa ati ole- jija. Ko feran elede, epo, emu, iyo, aja tabi omi ikasi   Orunmila ( IFA) ni olodumare fun ni ogbon, imo ati oye lati tun aye se. won gba pe o wa nibe nigba ti olodumare n se ipin ede. Idi niyi ti won fi n pe ni   Eleri-pin   Sango ti a tun n pe ni OLUFIRAN ti je oba alaafin oyo ri. Won gb...

IHUN ORO/SILEBU JSS2 (SECOND TERM )

        SILEBU ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si wewe.         IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.      Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere: 1.Silebu/ihun oro  lee waye gege bi  faweli. O le je faweli airanmupe tabi faweli      aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un. 2.Silebu/ihun oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe .Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl. 3.Silebu/ihun oro  le waye bii konsonanti aranmu asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.                                    ...

AWON EYA ARA - IFO SS1

  AKOLE ISE: ATUYEWO AWON EYA ARA - IFO (EYA ARA ISORO) Eya ara ifo ni eya ara ti a maa n lo fun gbigbe iro ifo jade A le pin eya ara ifo si isori meji, awon ni; Eya ara ifo ti a le fi oju ri: apeere: ete oke, ete isale, eyin oke, e yin isale, evigi, aja enu, iwaju a lo n, aarin lion, eyin ahon, afase, ita gongongo, olele, aja-enu, kaa imu Eya ara ifo ti a ko le fi oju ri: Apeere; Edo-foro, komookun, eka-komookun, tan-an-na, inu gogongo, kaa ofun. AWON EYA ARA TI A FI N PE IRO EDE AFIPE: Afipe ni gbogbo eya ara ifo ti won kopa ninu pipe iro ede jede. A le pin awon afipe wonyi si meji; awon nii APIPE ASUNSI: Eyi ni afipe ti o le gbera nigba ti a aba n pe iro won maa n sun soke sodo ti aban soro. Apeere; Afipe asunsi ni, Ete Isale, Eju isale, iwaju alion, aarin alion, eyin ahon, olele. AFIPE AKANMOLE: Eyi ni awon afipe ti ko le gbara soke sugbon ti won maa n duro gbari bi a ba n pe iro jade. Apeere afipe akonmole ni, ete oke, aja-enu, afase, iganna ofun, eyin oke, erigi, olele. Ipo t...