IJEYOPO ATI ANKOO FAWELI Ijeyopo faweli toka si asopo faweli ti ede kan fi aaye gba lati jo je yo po ninu oro onisilebu meji onihun. F1-KF2. Oro onisilebu meji onihun F1-KF2 tumo sip e ki F1 : duro fun faweli inu silebu akoko ati ohun re K : duro fun konsonanti inu silebu keji F2 : duro fun faweli inu silebu keji ato ohun re. Kii se gbogbo awon fawei ni won le je yo po bii. BATANI / IPO IJEYOPO F1 (faweli) F2 + F2- A i, e, e, a, o, o, u, an , un, in, on ((adi, ara, aje, adu, adan, abo, akin, arun, aro ) en E i, e, o, o, u, in, un ( eti, ewe, ejo, etu, egbin) e, a, o, en, on E i, e, a, o, an, in, on, un (eba, ewon, ete, ekun, erin) e, o, u, en I i, e, e, a,o,u,o,in,en,on,un,an ( iti, ito, ikin, ile, ipo, iyen, iyan, iwon) O
AROKO PIPA Aroko pipa je ona ti awon baba nla wa fi n ba ara won soro asiri lai fie nu so. Arin ni won fi n ranse si eniyan ti yoo si mo itumo re. Aroko kiko dabi leta ni aye ode – onu . ORISIIRISII AROKO AYE ATIJO 1. AALE – ni ami ti afile eru, esotabi eniyan lati fi kilo fun awon ole tabi eniyan ki o mase mu nnkan naa. Awon nikan aale ni wonyii – lkearahun igbin, Akisa aso, Aso pupa, Suku agbado, Erupe, okuta, oogun (Magun) thunder-boat) Ale paale si ara igi osan ati eso miran, oju ona, enu ibode ilu, ori aatan, inu oko abbl. 2. TESOO – Ni aale t a fi si ara omo ikose tabi omo ile – ire ki o bal aye kawe tabi kose re ja. 3. AAGA – Ni ami ti a ta mo ara igi meji ti a ri mole lati fi kilo funn eniyan lati sa fun ewu. Won meta ri tanaage si ori aatan, orille tabi oko ohun ti won n lo ni mariwo, ope, aso pupa, eni tabi okun agba ti a ta mo igi. 4. ITUFU – Ni awon nukan to le mu ina wa ti a gbe si eyinkille eniyan jau lati fi kilo fun ini eni bee ko won