Skip to main content

Posts

Showing posts from May, 2021

ITOJU ARA ATI AYIKA JSS3 (SECOND TERM)

Eyi ni sise ara eni losoo tabi sise ara loge. Iwa obun ni idakeji imototo. Awon Yoruba korira iwa obun pupo nitori pe o le fa aisan saye eni. ONA TI A LE GBA TOJU ARA ENI 1.    Iwe wiwe 2.   Enu fifo 3.   Irun didi tabi gige 4.   Eekanna gige 5.   Aso fifo 6.   Fifi adi agbon tabi ipara pa ara leyin iwe wiwe 7.    Itoju ounje wa 8.   Lilo ogun to ye : Ilokilo ogun ko dara ONA TI A GBA TOJU AYIKA WA 1.    Gbigba ile ayika 2.   Fifo ile iwe wa ati ile igbonse 3.   Gige tabi riro oko ayika wa 4.   Ile sisa kiri ayika ile wa 5.   Dida ile nu si ibi ti o to 6.   Yiye ona tori agbara ojo AWON OHUN ELO IMOTOTO Ose, Omi, Pako tabi Ifoyin, Kanin-kanin, Ipara,Igbale, Ada, Oko, abbl.

ITESIWAJU LORI IRO/AMIN OHUN JSS2 (SECOND TERM)

  Amin tabi iro ohun ni iro aseyato   laarin oro meji tabi ju bee lo ti won ni sipeli kan naa subgon   ti itumo won yato   Apeere Igba – (time)   D D Igba - (calabash) R M Igba- (garden egg) D M   Oko – (hoe) R M Oko – (canoe) R D Oko- (husband) R R     Owo- (money) R M Owo- (Trade) D D   Ogun- (war) R R Ogun- (inheritance) R M Ogun- (medicine) D D Ogun –( god of iron) D M Ere- (python) R D Ere-(play)   R M Ere –(profit)   D D   Owo –( honor) D D Owo – (broom) R D Owo –(hand) R M   Amin lori awon oro olopo silebu Ogede –(banana) D D D Ireke –( sugar cane) D D M Opolopo – (abundance) D D R D Alangba –(lizard) R M D M Patapata – (completely) M M M M Igbagbo –(belief) D D M Oronbo-(orange) D R D M Atanpako –(thumb) D D D D D

OGUN PINPIN TABI JIJE NI ILANA IBILE SS2 (SECOND TERM)

Ogun toka si ohun ti ologbe fi oogun oju re ko jo nigba aye re. Ohun ini bee le je owo, ile, oko, , eru,omo, iyawo  tabi awon dukia miiran. Ni ile Yoruba bi omo se le je ogun baba naa lo le je ti iya ra. Ogoji ojo leyin  ti oku ba ti ku ni won to le pin ogun re. Won yoo yan baba isinku o le je ebi to ba dagba julo, oun ni yoo seto isinku titi di akoko ti won yoo pin ogun. Baba isinku kii mu ninu ogun. Ki ogun pinpin to waye, baba isinku ati awon amulegbe re yoo ti seto bi gbogbo nnkan  yoo fi lo ni irowo-irose. Ohun akoko ni lati da ifa lati mo ojo ti o ye ati akoko lati fi ijoko si.   AWON TI WON LETOO SI OGUN Gbogbo awon omo oku ati awon omo iya re ti won je aburo ni won ni eto si ogun. Baba , iya, egbon oku ati iyawo ko ni eto lati pin ninu ogun oku ni ile Yoruba. AKOKO TI A N PIN OGUN Leyin isinku ni won yoo dajo ti won yoo pin ogun. Ogoji ojo gbodo pe ayafi ti ija ba wa ti won si fe fi pinpin ogun petu si ikun-sinu to wa nile. OJO IJOKOO OGUN PINPIN Ona ti a n gba pin ogun yato la

IHUN ORO/SILEBU JSS2 (SECOND TERM )

        SILEBU ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si wewe.         IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.      Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere: 1.Silebu/ihun oro  lee waye gege bi  faweli. O le je faweli airanmupe tabi faweli      aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un. 2.Silebu/ihun oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe .Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl. 3.Silebu/ihun oro  le waye bii konsonanti aranmu asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.                                             AWON BATANI IHUN ORO/SILEBU Faweli-F = ka, ma,gbo,ran,sun, fe,lo, abbl. Faweli ati konsonanti ati faweli-FKF = Aja, obe, Adan, Erin, Ife, Iku Konsonanti ati faweli ati konsonanti ati faweli- KFKF =  Baluwe, Salewa, Jagunjagun, Kabiesi Konsonanti Aranmupe asesilebu – KF-N-KF =   gogo n