SILEBU
ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si
wewe.
IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta
konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.
Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee
gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere:
1.Silebu/ihun
oro lee waye gege bi faweli. O le je faweli airanmupe tabi
faweli
aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un.
2.Silebu/ihun
oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe
tabi aranmupe
.Bi apeere :
sun,lo, de, gbin, to,ke abbl.
3.Silebu/ihun
oro le waye bii konsonanti aranmu
asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.
AWON BATANI IHUN ORO/SILEBU
Faweli-F =
ka, ma,gbo,ran,sun, fe,lo, abbl.
Faweli ati
konsonanti ati faweli-FKF = Aja, obe, Adan, Erin, Ife, Iku
Konsonanti ati
faweli ati konsonanti ati faweli- KFKF = Baluwe, Salewa, Jagunjagun, Kabiesi
Konsonanti
Aranmupe asesilebu – KF-N-KF = gogongo, gbangba, oronbo,konko,gbenga.
APEERE
SILEBU
A/de
o/ba
ko/la/wo/le.abbl.
Ko / n / ko
gba / n /gba
ba / n/ba
du /n /du
O/ ro / n
/bo
Oro olopo silebu – Oro kan le ni ju silebu kan le. Iru on
bee ni a n rpe ni oro olopo silebu.
Bi apeere silebu ihun iye silebu owo ‘o’ __ mo f – kf
meji
Ogede __ ‘o __ge __ de
meta
Igbala __ i _gba _la
meta
Oronbo __ O __ro _n _bo
merin
ekunrere _ e
_kun _ rere merin
Olopaa __ O
_ lo _ pa _ a merin
Akiyesi pakati
ti a se ni pe
1.
konsonanti
meji ko gbodo tele ara won ninu ede Yoruba
2.
konsonanti
ko le pari oro inu ede Yoruba.
Comments
Post a Comment