IJEYOPO
ATI ANKOO FAWELI
Ijeyopo faweli
toka si asopo faweli ti ede kan fi aaye gba lati jo je yo po ninu oro onisilebu
meji onihun. F1-KF2.
Oro onisilebu
meji onihun F1-KF2 tumo sip e ki
F1 : duro fun
faweli inu silebu akoko ati ohun re
K :
duro fun konsonanti inu silebu keji
F2 : duro fun faweli inu silebu keji ato ohun
re.
Kii se gbogbo
awon fawei ni won le je yo po bii.
BATANI / IPO IJEYOPO
F1 (faweli) |
F2 + |
F2- |
A |
i, e, e,
a, o, o, u, an , un, in, on ((adi, ara, aje, adu, adan, abo, akin, arun, aro
) |
en |
E |
i, e, o,
o, u, in, un (eti, ewe, ejo, etu, egbin) |
e, a, o, en, on |
E |
i, e, a,
o, an, in, on, un (eba, ewon, ete, ekun, erin) |
e, o, u, en |
I |
i, e, e,
a,o,u,o,in,en,on,un,an ( iti, ito,
ikin, ile, ipo, iyen, iyan, iwon) |
|
O |
i, e, o,
u, in, un (ori, odo, gu, oyin, oyun, oke) |
e, a, o, en, on |
O |
i, e, a,
o,an, in, on, un (oti, oga, okin, okun, awon) |
e, o, u, en |
U |
*********** |
*********** |
ANKOO FAWELI
Ankoo faweli
toka si ibi ti awon faweli ti won je yo tele ara won ninu oro ti maa n jo ni
abuda kan naa.
|
IWAJU |
AARIN |
EYIN |
AHANUPE |
I |
|
u |
AHANUDIEPE |
E |
|
o |
AYANUDIEPE |
E |
|
o |
AYANUPE |
|
a |
|
Pelu ate oke yii
batani meji ni ankoo faweli inu ede Yoruba pin si. Awon ni
·
AJEMOHANUPE
ati AJEMOYANUPE
·
FAWELI
IWAJU ati FAWELI EYIN
Bi apeere : ahanudiepe : e, o = eto, epo ayanudiepe : e, o = ejo, efo
Faweli iwaju (i,e,e) = ike, ete Faweli eyin (u,o,o) = oko, olu
Comments
Post a Comment