Skip to main content

OWO YIYA ATI ONA TI A FI N GBA GBESE (ss)

 


OWO YIYA ATI ONA TI A FI N GBA GBESE

Owo yiya je lara awon ona ti awon Yoruba gba ran ara won lowo ni atijo titi di ode –oni.

DIE NINU AWON IDI TI A FI N YSA OWO LAYE ATIJO.

1.      Oku baba tabi iya eni sisin

2.     Oku ana sisin

3.     Ile kiko

4.     Iyawo fife

5.     Aisan wiwo

6.     Fifi tan oran

AWON ONA TI A N GBA YAWO NI ATIJO

1.      Kiko owo ele

2.     Fifi nnkan duro tabi dogo

3.     Fifi omo kowo tabi sofa

DIE LARA AWON OFIN TO DE IWOFA

1.      Abo ise ni ise iwofa

2.     Iwofa kii se eru nitori naa o ni omonira tire

3.     Olowo ko gbodo ba iwofa obinrin lo, bi o ba se bee, o gbodo sanwo itanran.

DIE AWON ONA TI A N FI GBA GBESE LAYE ATIJO

1.      Sisin gbese funra olowo

2.     Didogo ti ajegbese ati fifooro emi re titi ti yoo fi sanwo.

3.     Riran elemu-un lo si ile ajegbese .

ORISII ONA TI A N GBA YAWO NI ODE-ONI.

1.      Owo yiya ni banki

2.     Lati inu Egbe Alafowosowopo

3.     Lati inu apo Egbe Alajo Dida

4.     Lowo Ajo ayanilowo sise tabi Ayanilowo kole.   

Comments

Popular posts from this blog

AWON ORISA ILE YORUBA

ISORI EKO : AWON ORISA ILE YORUBA Awon Yoruba gba awon orisa bii asoju tabi iranse olodumare, alarina, lagata tabi alagbewi ni won je. Ero awon Yoruba ni pe olorun feran awon orisa wonyi.   Okanlenirinwo ni awon orisa ile Yoruba . lara won ni Obatala, Orunmila, Esu, Sango, Ogun ati bee bee lo   Obatala ni awon Yoruba pe ni ALAMORERE . Won gbagbo pe oun ni o mo gbogbo eya ara eniyan ki olodumare to mi emi iye si inu won Funfun   ni awon ohun elo obatala, lara won ni ileke funfun, aso funfun, bata funfun. Ounje ti o feran julo ni obe ate ( obe ti ko ni iyo ), igbin ati iyan. Omi ajipon ni obatala maa n mu. Ko feran iwa aito bi iro pipa ati ole- jija. Ko feran elede, epo, emu, iyo, aja tabi omi ikasi   Orunmila ( IFA) ni olodumare fun ni ogbon, imo ati oye lati tun aye se. won gba pe o wa nibe nigba ti olodumare n se ipin ede. Idi niyi ti won fi n pe ni   Eleri-pin   Sango ti a tun n pe ni OLUFIRAN ti je oba alaafin oyo ri. Won gb...

IHUN ORO/SILEBU JSS2 (SECOND TERM )

        SILEBU ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si wewe.         IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.      Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere: 1.Silebu/ihun oro  lee waye gege bi  faweli. O le je faweli airanmupe tabi faweli      aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un. 2.Silebu/ihun oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe .Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl. 3.Silebu/ihun oro  le waye bii konsonanti aranmu asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.                                    ...

AWE GBOLOHUN (JSS)

 AWE GBOLOHUN   AWE GBOLOHUN ni ipede to ni oluwa ati ohun ti oluwa n se . ona meji Pataki ni awe gbolohun pin si . Olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe, Olori awe gbolohun maa n da duro, yoo si ni itumo, o si maa n sise gbolohun abode. Apeere   1) Ola ti sun                2) Mo n bo   Awe gbolohun afarahe tabi afibo : eyi ni gbolohun ti ko le da duro ko si fun wa ni itumo, o maa darale olori gbolohun ni, o si maa n wonpo ninu gbolohun olopo oro ise ( onibo )   Lara awon atoka gbolohun afarahe ni : ti, pe, ki, iba, bi, boya, tabi ati bee bee lo. Awe gbolohun le wa ni   ibeere, aarin tabi ipari gbolohun. Isori meta ni a le pin si. Awon si ni : 1.     ASODORUKO 2.     ASAPEJUWE 3.     ASAPONLE AWE GBOLOHUN ASODORUKO : eyi ni odidi gbolohun ti a so di oro-oruko nipa lilo oro atoka   “PE” Apeere   : ...