Skip to main content

Posts

SISE AGBEYEWO LITIRESO APILEKO SSS2 (FIRST TERM)

  SISE AGBEYEWO LITIRESO APILEKO Litireso apileko ni awon iwe ewi, onitan aroso tabi ere onitan ti onkowe ko sile fun kika, Pataki julo fun idanilekoo ati idanilaraya IDI TI A FI N KOWE LITIRESO APILEKO 1.      Lati fi da awon eniyan lara ya. 2.      Lati fi ko awon eniyan logbon 3.      Lati yege ninu idanwo 4.      Lati mu ki eniyan ronu ni ona ti o ye ko ro 5.      Lati fi on aero tun aidara ilu ati iwa omo araye se 6.      Lati fi asa ibile, iriri awon eniyan ati igbagbo won han. Litireso apileko pin si ona meta:                       I.           Ewi     II.           Itan aroso   III.        ...

Eto Iselu Abinibi Nile Yoruba SSS2 (FIRST TERM )

  ISORI EKO : Eto Iselu Abinibi Nile Yoruba Ki awon oyinbo to de ile Yoruba ni awon babanla wa ti ni   eto oselu to fi   ese mule gboingboin. Eto oselu beere lati inu ile. Ipa ti baale ile, iyaale ile, obinrin ile, omo ile, awon oloye ati oba ilu ko ninu eto oselu ko kere. Awon ni won mu ilu ro nipa eto idajo ododo, aabo to gbamuse, igbega ati   idagbasoke to se mu yangan. AATO AGBBO ILE Eto ogbole ni ipinle   eto iselu ni ile Yoruba. Agbole ni ibe ti awon ebi tabi alajobi n gbe papo. Baba, iya, egbon , awon omo ati awon ibatan ti won to ese baba waye. Agbole ile le to mewa si meedogun. Bi agbole ba se tobi si ni awon eniyan ibe se maa n po si. Olori agbole ni baale. Oye idile ni, eni ti o ba dagba ju lo ninu ile ni n je oye baale. ISE BAALE ILE 1.       Aawo pipari 2.       Alejo gbigba 3.       Lile alejo to ba se kuro ni agbo ile 4.       Adar...

ASANYAN EWI ALOHUN FUN ITUPALE SSS2 (FIRST TERM )

  ASANYAN EWI ALOHUN FUN ITUPALE Ki a to so nipa ewi tabi litireso alohun, a gbodo koko mo ohun ti ewi tabi litireso je. Litireso/Ewi ni akojopo ijinle, ogbon , asa ati ise Yoruba, o je ero okan tabi irir eni lori nnkan bii eniyan, ohun elemi tabi alailemi ti a gbe kale lawujo lati ko ni logbon. LITIRESO ni ise atinuda awon oloye lati inu iriri ati akiyesi fun idanileko ati idanilaraya. Litireso/ewi pin si ona meji   : 1.      Litireso/ewi alohun 2.      Litireso/ewi apileko   Litireso/ewi alohun : je ewi ajogunba ti a n fi ohun didun gbe jade lenu. Ona meta lo pin si EWI ALOHUN                   ITAN                                                           AJEMESIN...

ATUNYEWO GBOLOHUN SSS2 ( FIRST TERM)

  ISORI EKO : GBOLOHUN GBOLOHUN : Eyi ni ipede ti o kun, ti o ni ise ti o n je tabi se, ti o si ni itumo. Orisi ona ni a le pin gbolohun si ninu ede Yoruba.   AWON ONIRUURU GBOLOHUN   GBOLOHUN ELEYO ORO ISE ( Gbolohun abode) : Segun fe iyawo   GBOLOHUN OLOPO ORO ISE :   Ade lo si ile ki o to jeun ni ana   GBOLOHUN IBEERE :   Se o ti jeun ,    Ewo lo wun o   GBOLOHUN KANI : Bi mo ba ni owo maa ra oko   GBOLOHUN ASE : E dide jokoo   GBOLOHUN AYISODI :Bola ko wa si ile-eko   GBOLOHUN ALAKANPO :Olu wa sugbon ko jeun   GBOLOHUN ONIBO : Aso ti mo ra ti ya   Gbolohun alakanpo ni siso gbolohun abode meji papo pelu awon wuren bi sugbon, ati, tabi, ati bee bee lo.           Apeere : Olu wa + Olu ko sun = Olu wa sugbon ko sun Gbolohun alakanpo maa ni ju oro-ise kan lo           Apeere : O...