ASANYAN EWI
ALOHUN FUN ITUPALE
Ki a to so
nipa ewi tabi litireso alohun, a gbodo koko mo ohun ti ewi tabi litireso je.
Litireso/Ewi
ni akojopo ijinle, ogbon , asa ati ise Yoruba, o je ero okan tabi irir eni lori
nnkan bii eniyan, ohun elemi tabi alailemi ti a gbe kale lawujo lati ko ni
logbon.
LITIRESO ni ise atinuda awon
oloye lati inu iriri ati akiyesi fun idanileko ati idanilaraya.
Litireso/ewi pin si ona meji :
1.
Litireso/ewi
alohun
2.
Litireso/ewi
apileko
Litireso/ewi alohun: je ewi ajogunba ti a n fi ohun didun gbe
jade lenu. Ona meta lo pin si
EWI
ALOHUN
ITAN AJEMESIN AJEMAYEYE
Alo
apamo |
Ijala |
Rara |
|
Esa/iwi |
Dadakuada |
Alo
apagbe |
Oya
pipe |
Biripo |
|
Sango
pipe |
Ekun
iyawo |
|
Esu
pipe |
Adamo |
EWI
ALOHUN |
AWON TI WON N LO (AKOPA) |
Iyere
Sisun |
Babalawo |
Iwi/Esa
Egungun |
Oje/Elegun |
Esu
Pipe |
Elesu |
Oya
Pipe |
Oloya |
Ijala/
Iremoje |
Ode |
Arungbe |
Oloro |
Sango
Pipe |
Onisango/Adosan |
Atupale
Asayan Ewi Alohun
Ti a ba fe
se atupale asayan ewi alohun, awon ohun ti a gbodo mo ni wonyii
1. Oriki ewi
alohun
2. Orisi ewi
alohun
3. Awon ohun ti
a le fid a ewi kookan mo. Apeere :- Ilu, Osere, Akoko isere, Akoonu, Abuda
adani.
4. Adugbo ti
okookan ti wo po. Gege bi apeere ewi alohun ajemayeye.
ISARE FUN AYEYE |
ILU TABI AGBEGBE |
Rara |
Oyo |
Etiyeri
|
Oyo |
Ekun
iyawo |
Oyo |
Bolojo
|
Yewa
(egbado ) |
Igbala
|
Egba
(Abeokuta) |
Ege
/Ariwo/Orin agbe |
Egba |
Obitun |
Ondo |
Alamo |
Ekiti |
Dadakuada
|
Igbomina
/Ilorin |
Olele |
Ijesa |
Biripo
|
Ikale |
Apepe |
Ijebu |
Agase |
Awori |
Adamo |
Ife |
Ilo-ede
:- A o ri orisirisi ona ewa ede ti won lo bi afiwe eleloo, afiwe taata,
ifohunpeniyan,awitunwi,eyo oro,olodindi gbolohun, apola gbolohun, abbl.
Comments
Post a Comment