ISORI EKO :
GBOLOHUN
GBOLOHUN :
Eyi ni ipede ti o kun, ti o ni ise ti o n je tabi se, ti o si ni itumo. Orisi
ona ni a le pin gbolohun si ninu ede Yoruba.
AWON ONIRUURU GBOLOHUN
GBOLOHUN
ELEYO ORO ISE ( Gbolohun abode) : Segun fe iyawo
GBOLOHUN
OLOPO ORO ISE : Ade lo si ile ki o to
jeun ni ana
GBOLOHUN
IBEERE : Se o ti jeun , Ewo lo wun o
GBOLOHUN
KANI : Bi mo ba ni owo maa ra oko
GBOLOHUN ASE
: E dide jokoo
GBOLOHUN
AYISODI :Bola ko wa si ile-eko
GBOLOHUN
ALAKANPO :Olu wa sugbon ko jeun
GBOLOHUN
ONIBO : Aso ti mo ra ti ya
Gbolohun alakanpo ni siso
gbolohun abode meji papo pelu awon wuren bi sugbon, ati, tabi, ati bee bee lo.
Apeere : Olu wa + Olu ko sun = Olu wa
sugbon ko sun
Gbolohun alakanpo maa ni ju
oro-ise kan lo
Apeere : Olu lo si oja sugbon ko ri
ata ra
GBOLOHUN ONIBO
Gbolohun onibo ni gbolohun ti a
fi gbolohun kan bo inu gbolohun miran
Apeere ihun gbolohun onibo
· Olori gbolohun
--- Aso ti ya
· Gbobohun afibo ---
ti mo ra
· Gbolohun onibi = aso ti mo ra ti
ya
· Olori gbolohun = oko naa wu mi
· Gbolohun afibo = ti ola ra
· Gbolohun onibo = Oko naa ti ola
ra wu mi
Comments
Post a Comment