SISE
AGBEYEWO LITIRESO APILEKO
Litireso
apileko ni awon iwe ewi, onitan aroso tabi ere onitan ti onkowe ko sile fun
kika, Pataki julo fun idanilekoo ati idanilaraya
IDI
TI A FI N KOWE LITIRESO APILEKO
1. Lati fi da
awon eniyan lara ya.
2. Lati fi ko
awon eniyan logbon
3. Lati yege
ninu idanwo
4. Lati mu ki
eniyan ronu ni ona ti o ye ko ro
5. Lati fi on
aero tun aidara ilu ati iwa omo araye se
6. Lati fi asa
ibile, iriri awon eniyan ati igbagbo won han.
Litireso
apileko pin si ona meta:
I.
Ewi
II.
Itan aroso
III.
Ere onitan
ABUDA LITIRESO APILEKO
1.
Koko itan:-
eyi ni ogbon atinuda ti onkowe lo lati hun itan re po di odindin
2.
Ibudo itan
:- eyin ni awon ibi kookan ti isele inu itan ti sele, O le je adugbo tabi
abule, inu igbo tabi eyin odi ilu.
3.
Eda itan ati
Ifiwaweda :- eyi ni awon akopa inu itan, olu eda itan ni ipo tire maa po ju.
4.
Ilo-ede:-itan
aroso gbodo ni ede Yoruba to jiire bii owe, akonli ede, afiwe, awitunwi,
asodun, ifohunpeniyan,ifohundara,abbl.
5.
Asa :- Bii
asa igbeyawo, Isomoloruko,Oye jije,abbl.
6.
Ibayemu:- se
isele inu iwe ti a ka ba isele aye mu regi tabi bee ko. Eyi ti o ba isele oju
aye mu maa n dun un ka .
7.
Eko ti o ko
ni.
Ogbon
isotan:- onkowe le lo ogbon arinurode, oju-mi-lose,Isoro-gbese ati itan ninu
itan
Comments
Post a Comment