ORAN ATI
IDAJO TI O TO
Awon Yoruba
ni igbagbo ninu idajo ododo, won ki i si n fi ejo se egbe. Gbogbo oran ni o ni
ijiya to to labe isakoso ijoba laye ojoun, amo bi o tile je pe eto ofin fi ese
mule ni aye awon baba nla wa, sibe nwon igba to je pe ko si eto bi-mi-ki-bi-e
tabi eko ofin iru ti ode oni, opolopo awon ti ko mowo mese maa saba jiya ese ti
elomiran da. Eyi lo mu ki awon babanla wa maa
pe “ Ori yeye ni mogun, ipin aise lo po ni be.”
Eyi ni ate
apeere oran ati ijiya fun okookan ni aye atijo.
ORAN |
IJIYA TABI
IDAJO |
Ipaniyan |
Bibe ori
iodaran si Mogun |
Ifadiya |
Mimu
odaran sanwo itanran bi o ba onile, bi o ba je alejo, sisan owo itanran ati
lile kuro ni ilu pelu |
Jibiti
lilu |
Dida owo
pada ati sisan owo itanran. bi o ba je alejo, sisan owo itanran ati lile kuro
ni ilu pelu |
Gbigba emi
ara eni lainide Gbigba emi
ara eni bi akin |
Sisin
laisi ayeye. Awon oloro yoo fi se etutu Ko si
ijiya lodo enikeni |
Agbere sise.
Biba iyawo oniyawo sun |
Ikilo/Nina
legba ni gbangban ode. Lile kuro ni ilu]0 to ba je alejo. |
Ole jija/
Eni ba tori ebi jale |
Egba lasan |
Aiba iyawo
eni nile |
Itiju/
Abuku |
Iro pipa
lati bo asiri eni, ba eni keji je |
Sisan owo
itanran |
Ote sise
mo Oba, ijoye tabi ilu |
Iku ni
idajo |
IRENIJE :
Oba ilu ti ko ka ara ilu si |
Ikilo ni
igboro. Fifi kirikiri gbe oba ti ko ba yi pada |
Ijoye to
se aidara |
Riro loye
ni ijiya. |
Comments
Post a Comment