ISE AGBE
Ise agbe je
ise ti o gbajumo ju lo ni ile Yoruba.Ise agbe se Pataki nitori awon ni won n
pese ounje fun ara ilu. Awon agbe ni won n gbin ere oko bii paki, ere/ewa,
isu,agbado,ata, efo ewedu,epa ati bee bee lo.A le pin agbe si orisi meji .
(i)
Agbe
Alaroje (small scale faming) :Agbe alaroje ni awon agbe kekeke ti won n da oko
etile fun jije ara won.
(ii)
Agbe
Aldaa-nla (large scale farming) :Agbe Alada-nla ni awon ti won n dako egan,ti
won n fi ise agbe sise se.
ISE ILU LILU
Ise abinibi
ni ise ilu lilu je fun awon iran ayan.kaakiri ile Yoruba ni ise yii gbajumo.Ibi
ti won ti n se nnkan eye,odun ibile,ni won ti n lulu.Amuludun ni awon onilu
je.Ibi ti won ba ti n lu ilu,orin ati ijo kii gbeyin nibe.Ise idile ni ise ayan
je sugbon won tun maa koi se ilu naa.
A le pin ilu
si meji gege bi lilo won.Awon ni :
1)
Ilu
fun Odun Ibile
2)
Ilu
fun Ayeye
ILU FUN ODUN
IBILE :
ILU |
ORISA TO NI |
Bata |
Sango, Egungun |
Ipese/ipesi |
Ifa |
Agere |
Ogun |
Igbin |
Obatala |
ILU FUN AYEYE :
Dundun |
(neta ni
won) Awon ni iya ilu,kerikeri,Gangan,Omele,Kannango,Gudugudu |
Awon
miiran |
Ibenbe,Kiriboto,Gbedu,Koso,Apini
(meta ni ) Iya-ilu Omele ati
Agogo, Sakara,Sanba,Apepe,Agogo,Agidigbo,Sekere |
Comments
Post a Comment