Skip to main content

AWON EYA YORUBA JSS 1



AWON EYA YORUBA  

Awon eya Yoruba ni awon ti won gba Oduduwa gege bi babanla won, ti won si n so ede Yoruba gege bi ede abinibi

AWON EYA YORUBA

ILU ABE WON

OUNJE WON

1.   OYO

OYO, IBADAN, OGBOMOSO, IWO, EJIGBO, IKOYI-ILE

 EKO YANGAN, AMALA ATI GBEGIRI

2.   EGBA

ABEOKUTA, OWU, IBEREKODO GBEGURA, OKE-ONA

AMALA FUNFUN

3.   IFE

ILE-IFE, IFETEDO, OKE-IGBO,

AMALA OGEDE

4.   IJESA

ILESA, ESA-OKE, IJEBU-IJESA

IYAN, AKARA

5.   EKITI

ADO, IJERO, IMESI-OKE

IYAN & EGUSI

6.   ONDO

ONDO, ILE-OLUJI, IDANRE

IYAN

7.   ILORIN

ILORIN , LADUBA, AFON

TUWO

8.   EKO

ISALE-EKO, OSODI, AGEGE

EJA, EDE

9.   IJEBU

 IJEBU-ODE, AGO-IWOYE, EPE, SAGAMU

IKOKORE, GAARI

 

AWON OBA ALADE WONYII TEDO SI ILU YII

ORUKO OYE

ILU

OSEMAWE

ONDO

EBUMAWE

AGO-IWOYE

OLOWO

OWO

OWA AJAKA

OSOGBO

AKARIGBO

REMO

 

 

Comments

Popular posts from this blog

AWON ORISA ILE YORUBA

ISORI EKO : AWON ORISA ILE YORUBA Awon Yoruba gba awon orisa bii asoju tabi iranse olodumare, alarina, lagata tabi alagbewi ni won je. Ero awon Yoruba ni pe olorun feran awon orisa wonyi.   Okanlenirinwo ni awon orisa ile Yoruba . lara won ni Obatala, Orunmila, Esu, Sango, Ogun ati bee bee lo   Obatala ni awon Yoruba pe ni ALAMORERE . Won gbagbo pe oun ni o mo gbogbo eya ara eniyan ki olodumare to mi emi iye si inu won Funfun   ni awon ohun elo obatala, lara won ni ileke funfun, aso funfun, bata funfun. Ounje ti o feran julo ni obe ate ( obe ti ko ni iyo ), igbin ati iyan. Omi ajipon ni obatala maa n mu. Ko feran iwa aito bi iro pipa ati ole- jija. Ko feran elede, epo, emu, iyo, aja tabi omi ikasi   Orunmila ( IFA) ni olodumare fun ni ogbon, imo ati oye lati tun aye se. won gba pe o wa nibe nigba ti olodumare n se ipin ede. Idi niyi ti won fi n pe ni   Eleri-pin   Sango ti a tun n pe ni OLUFIRAN ti je oba alaafin oyo ri. Won gb...

IHUN ORO/SILEBU JSS2 (SECOND TERM )

        SILEBU ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si wewe.         IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.      Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere: 1.Silebu/ihun oro  lee waye gege bi  faweli. O le je faweli airanmupe tabi faweli      aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un. 2.Silebu/ihun oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe .Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl. 3.Silebu/ihun oro  le waye bii konsonanti aranmu asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.                                    ...

AWON EYA ARA - IFO SS1

  AKOLE ISE: ATUYEWO AWON EYA ARA - IFO (EYA ARA ISORO) Eya ara ifo ni eya ara ti a maa n lo fun gbigbe iro ifo jade A le pin eya ara ifo si isori meji, awon ni; Eya ara ifo ti a le fi oju ri: apeere: ete oke, ete isale, eyin oke, e yin isale, evigi, aja enu, iwaju a lo n, aarin lion, eyin ahon, afase, ita gongongo, olele, aja-enu, kaa imu Eya ara ifo ti a ko le fi oju ri: Apeere; Edo-foro, komookun, eka-komookun, tan-an-na, inu gogongo, kaa ofun. AWON EYA ARA TI A FI N PE IRO EDE AFIPE: Afipe ni gbogbo eya ara ifo ti won kopa ninu pipe iro ede jede. A le pin awon afipe wonyi si meji; awon nii APIPE ASUNSI: Eyi ni afipe ti o le gbera nigba ti a aba n pe iro won maa n sun soke sodo ti aban soro. Apeere; Afipe asunsi ni, Ete Isale, Eju isale, iwaju alion, aarin alion, eyin ahon, olele. AFIPE AKANMOLE: Eyi ni awon afipe ti ko le gbara soke sugbon ti won maa n duro gbari bi a ba n pe iro jade. Apeere afipe akonmole ni, ete oke, aja-enu, afase, iganna ofun, eyin oke, erigi, olele. Ipo t...