OWO SISE
Owo sise ni a mo si karakata. O je okan pataki ninu ise aje awon yoruba.
Pataki owo sise
1. Owo sise ni n le ise danu, o si n soni dolowo
2. O n je ki a ni ise lowo
3. Owo kii je ki a sole
4. O mu ni gbajumo ni awujo
5. O mu ki oja okere wa ni arowoto wa
6. O mu ki ire oko wo ilu ni opo yanturu
Orisi owo ti yoruba n se .
1. AROBO/AGBATA : awon alarobo ni won n raja lowo oloko, won yoo wa ta ojo naa fun
awon Alajapa leyin igba ti won ba ti fi owo le e.
2. ALAJAPA : won n ra ojo lowo oloko tabi Alarobo, won yoo ta oja naa fun ara
ilu. Awon oja bi :Elubo, ata,isu,gaari,agbado, abbl.
3. Worobo/Wosiwosi : eyi ni awon ti won n taja pepeepe tabi worobo. Won le pate oja won
tabi ki won kiri oja won. Awon oja bii :- Suiti,Bisikiti. Ose-iwe ati
ifoso, Pako,Aso omode,abbl.
4. OUNJE TITA- o leje ounje sise tabi tutu, won la pate tabi ki won kiri. Apeere ounje
bee ni : isu, iresi,epo,ewa abbl.
5. OSIN ERAN : awon onisowo kan wa ti won n ta eran osan lorisirisi bii :
Ewure, adiye,agbo,igbin,aguntan,abbl.
Comments
Post a Comment