ORIN IBILE
Orin ni
afo ti a fi ohun to dun ko ni eti sita.
ORISIRISI
ORIN IBILE
1. Orin ibi
igbeyawo
2. Orin
eremode
3. Orin oye
jije
4. Orin
ikomojade
5. Orin
amuseya
6. Orin
funeko iwa rere
1. ORIN IBI IGBEYAWO :
Eyi ni orin ti a n ko nibi ayeye igbeyawo, o
je orin ti won fi n ko iyawo afesona tabi olomoge ni ogbon ati eko.
ANFAANI
i.
n je ki obinrin mo iyi pipa ogo obinrin mo
ii.
n je ki a ni emi imore si obi
iii.
n ke ki omobinrin mo ojuse re si oko ati si ebi oko re
Apeere orin igbeyawo ni :- Baba mo n lo, fadura sin
mi o. Ori iya mi bu lomo, esuru kii ya agan o.
2. ORIN EREMODE :- eyi ni orin to maa n waye laaarin awon
ewe.
ANFAANI
i.
wa fun idaraya
ii.
n mu opolo ji pepe
iii.
mu ki omode gbagbe abuku tabi iya ara won
iv.
mu won mo Pataki itoju ara ati ayika
Apeere :-
Orin boju boju,… Eni bi eni… We ki o mo…..
3. ORIN NIBI OYE JIJE :- eyi ni orin ti
maa n gbo nibi ti won ti n se ayeye oye jije.
ANFAANI..
i.
n je ki a mo bi a se le gbe igbesi aye iwa rere lawujo
ii.
n je ka gbe asa abinibi laruge
4. ORIN IKOMOJADE : Eyi ni orin ti a n ko nibe ayeye
ikomojade.
ANFAANI
i.
n je ki a mo Pataki omo ikoko ninu ebi
ii.
wa fun gbigbe asa wa laruge
5. ORIN EKO IWA RERE :- eyi je orin iwuri
fun awon omode
ANFAANI
i.
ma mu ki omode tepa mose
ii.
ma ko omode ni iwa to to lati hu ni awujo
iii.
maa n ko awon omode ni asa
abinibi
Apeere :-
Omo to mo iya re loju…….
6. ORIN IREMOLEKUN : - Eyi ni orin ti abiamo fi n ro omo
eyin lekun.
ANFAANI
i.
mu ki omo dake ekun
ii.
je ona lati da omo laraya.
Apeere :-
omo mi o, akurubele ku be……….
ORIN AMUSEYA :- Eyi ni orin ti awon osise maa n ko
lenu ise.
ANFAANI
i.
je ona idaraya
ii.
mi ni mo riri ise eni
Comments
Post a Comment