Skip to main content

ONKA 1 - 400 YORUBA JSS1 (FIRST TERM)

 


ISORI EKO : (ONKA) OOKANLA  DE  IRINWO

OOKAN DE OGUN

FIGO

ONKA

FIGO

ONKA

1

Ookan

11

Ookanla

2

Eeji

12

Eejila

3

Eeta

13

Eetala

4

Eerin-in

14

Eerinla

5

Aarun un

15

Aarundinlogun

6

Eefa

16

Eerindinlogun

7

Eeje

17

Eetadinlogun

8

Eejo

18

Eejidinlogun

9

Eesan-an

19

Ookandinlogun

10

Ewa

20

OGUN

 

OOKANLELOGUN  DE OGBON

FIGO

ONKA

FIGO

ONKA

21

Ookanlelogun

40

OGOJI

22

Eejilelogun

50

AADOTA

23

Eetalelogun

60

OGOTA

24

Eerinlelogun

70

AADORIN

25

Aarundinlogbon

80

OGORIN

26

Eerindinlogbon

90

AADORUN –UN

27

Eetadinlogbon

100

OGURUN –UN S

28

Eejidinlogbon

 

 

29

Ookandinlogbon

 

 

30

OGBON

 

 

 

100 + 1 = ookan lelogurun-un = 110

100 + 2 = eejilelogorun-un = 112

100 + 3 = eetalelogorun-un = 113

100 + 4 = eerinlelogorun-un = 114

110 - 5 = aarun dinlaadofa = 115

110 - 4 = eerin dinlaadofa = 116

110 - 3 = eeta dinlaadofa = 117

110 - 2 = eeji dinlaadofa = 118

110 – 1 = ookan dinlaadofa = 119

110       = aadofa

Bayi ni a o maa lo ilana aropo (+), ayokuro ninu isori onka de ori igba (200)

100       20  x 5  = ogorun-un   

110       120 – 10 = aadofa             

120        20 x 6 =  ogofa  

130        140 – 10 =  aadoje                        

140       20 x 7  = ogoje

150        160 -  10 = aadojo                             

160       20 x 8 =  ogojo

170       180  -  10 =  aadosan –an

180      20 x 9  = ogosan 

190      20 x 9  = aadowa

200      20 x 10  = ogowaa/ Igba

Ni onka yoruba bi ogun (20) ba ti n wani ilopo ilopo, bayii ni a se n pe ilopo kookan le yin igba (200)

20 (ogun) ni a n pe ni Okoo

40 (ogoji) ni a n pe ni oji

60 (ogota) ni a n pe ni ota tabi ota

80 (ogorin) ni a n pe ni orin tabi orin

Amulo ilana isori, ayokuro ninu onka yoo lo bayii.

210 ( 220  -  10 )  =      Okoolerugba o din mewaa

211 ( 220  -  9 )  =        Okoderugba o din mesan-au

212 ( 220  -  8 )  =        Okoderugba o din mejo

213 ( 220  - 7 )  =         Okoolerugba o din meje

214 (220  -  6 )  =         Okoolerugba o din mefa

215 ( 220  -  5 )  =        Okoolerugba o din marun-un

216 ( 220  -  4 )  =        Okoolerugba o din merin

217 ( 220  -  3 )  =        Okoolerugba o din meta

218 ( 220  -  2 )  =        Okoolerugba o din meji

219 ( 220  -  1 )  =        Okoolerugba o din ookan

 

Apeere lilo ilana isiro ilopo ogun

220 ( 200  +  20 )  =     Okoolerugba / okoolenigba

240 ( 200  +  40 )  =     Ojileerugba / ojilenigba

260 ( 200  +  60 )  =     Otaleerugba / Otalenigba

280 ( 200  +  80 )  =     Orinleerugba / orinlenigba

300 ( 200  +  100 )  =  Oodunrin / oodun

320 ( 300  +  20 )  =     Okooleloodinrin

340 ( 300  +  40 )  =     Ojileloodunrun

360 ( 300  +  60 )  =     Otaleloodunrun

380 ( 300  +  80 )  =     Orinleloodunrun

400 ( 200  x  20 )  =     Igbameji / irinwo

Comments

Popular posts from this blog

IHUN ORO/SILEBU JSS2 (SECOND TERM )

        SILEBU ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si wewe.         IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.      Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere: 1.Silebu/ihun oro  lee waye gege bi  faweli. O le je faweli airanmupe tabi faweli      aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un. 2.Silebu/ihun oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe .Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl. 3.Silebu/ihun oro  le waye bii konsonanti aranmu asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.                                    ...

AWON ORISA ILE YORUBA

ISORI EKO : AWON ORISA ILE YORUBA Awon Yoruba gba awon orisa bii asoju tabi iranse olodumare, alarina, lagata tabi alagbewi ni won je. Ero awon Yoruba ni pe olorun feran awon orisa wonyi.   Okanlenirinwo ni awon orisa ile Yoruba . lara won ni Obatala, Orunmila, Esu, Sango, Ogun ati bee bee lo   Obatala ni awon Yoruba pe ni ALAMORERE . Won gbagbo pe oun ni o mo gbogbo eya ara eniyan ki olodumare to mi emi iye si inu won Funfun   ni awon ohun elo obatala, lara won ni ileke funfun, aso funfun, bata funfun. Ounje ti o feran julo ni obe ate ( obe ti ko ni iyo ), igbin ati iyan. Omi ajipon ni obatala maa n mu. Ko feran iwa aito bi iro pipa ati ole- jija. Ko feran elede, epo, emu, iyo, aja tabi omi ikasi   Orunmila ( IFA) ni olodumare fun ni ogbon, imo ati oye lati tun aye se. won gba pe o wa nibe nigba ti olodumare n se ipin ede. Idi niyi ti won fi n pe ni   Eleri-pin   Sango ti a tun n pe ni OLUFIRAN ti je oba alaafin oyo ri. Won gb...

AWE GBOLOHUN (JSS)

 AWE GBOLOHUN   AWE GBOLOHUN ni ipede to ni oluwa ati ohun ti oluwa n se . ona meji Pataki ni awe gbolohun pin si . Olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe, Olori awe gbolohun maa n da duro, yoo si ni itumo, o si maa n sise gbolohun abode. Apeere   1) Ola ti sun                2) Mo n bo   Awe gbolohun afarahe tabi afibo : eyi ni gbolohun ti ko le da duro ko si fun wa ni itumo, o maa darale olori gbolohun ni, o si maa n wonpo ninu gbolohun olopo oro ise ( onibo )   Lara awon atoka gbolohun afarahe ni : ti, pe, ki, iba, bi, boya, tabi ati bee bee lo. Awe gbolohun le wa ni   ibeere, aarin tabi ipari gbolohun. Isori meta ni a le pin si. Awon si ni : 1.     ASODORUKO 2.     ASAPEJUWE 3.     ASAPONLE AWE GBOLOHUN ASODORUKO : eyi ni odidi gbolohun ti a so di oro-oruko nipa lilo oro atoka   “PE” Apeere   : ...