ALIFABEETI EDE YORUBA
kini iro Ede Yoruba(Speech sounds)? – Iro ede ni ege to o kere ju
lo ti ale fi eti gbo ninu ede,awon si ni oro ti a n lo fun akoto ede Yoruba. Eyi ni iro ohun to
kere julo ti a le fi eti gbo, bakanna awon won ni a n pe ni alifabeti Yoruba.
Awon si ni
Aa Bb Dd
Ee Ee Ff
Gg GBgb Hh
Ii Jj Kk
Ll Mm
Nn Oo Oo Pp Rr
Ss Ss Tt
Uu Ww Yy
Alifabeti ede Yoruba je
marunlelogun (25)
A LE PIN ALIFABETI EDE YORUBA SI ONA MEJI
1. KONSONANTI : eyi ni
awon iro ti won ko le da duro ninu ede Yoruba. Ko si le ni itumo lai je pe a fi iro miiran mo on. Bi idi w oba wa fun
eemi(Air stream) ti
o n bo lati inu edo- foro ni enu, iro ede ti a o pe ni iro
kononanti
Eyi Ni Awon Konsonanti Ede Yoruba:
Bb Dd
Ff Gg GBgb
Hh Jj Kk
Ll Mm
Nn Pp Rr Ss Ss
Tt Ww Yy
2. FAWELI : eyi ni iro
yoowu ti a n pe lai si idiwo fun eemi(Air stream) ti o n bo lati inu edo-foro(lungs). Awon wonyii le da duro gege bi silebu tabi oro to ni itumo
AWON FAWELI PIN SI ONA MEJI
A) FAWELI
ARUNMUPE : -Faweli aranmupe je meje (7) A E E
I O U
(B) FAWELI AIRANMUPE:- Faweli aIranmupe je marun-un (5) AN EN IN ON UN
Comments
Post a Comment