KINI SILEBU :
Silebu ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je
gige oro si wewe.
IHUN SILEBU
Orisirisi ona ni silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere:
1.Silebu lee waye gege bi faweli.O le je faweli airanmupe tabi
faweli
aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un.
2.Silebu tun le waye gege bi apapo konsonanti
ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe
.Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl.
3.Silebu le waye bii konsonanti aranmu
asesilebu.N ATI M .b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.
AWON ORO SILEBU
Faweli-F, Efo, Ile , Okom Adugbo
Faweli ati konsonanti – KF Baluwe, Salewa,
Jagunjagun, Kabiesi
Konsonanti Aranmupe asesilebu – N gogongo,
APEERE SILEBU
A/de
o/ba
ko/la/wo/le.abbl.
Ko / n / ko
gba / n /gba
ba / n/ba
du /n /du
O/ ro / n /bo
Oro olopo silebu
– Oro kan le ni ju silebu kan le. Iru on bee ni a n pe ni oro olopo silebu.
Bi apeere
silebu ihun iye silebu owo ‘o’ __ mo f – kf (meji)
Ogede __ ‘o
__ge __ de (meta)
Igbala __ i
_gba _la (meta)
Oronbo __ O
__ro _n _bo (merin)
ekunrere _ e _kun _ rere (merin)
Olopaa __ O _ lo _ pa _ a (merin)
Comments
Post a Comment