ESIN IBILE ATI IPA PATAKI TI ESIN N KO LAWUJO
Esin
ibile ni ona ti a n gba sin Olorun ni ilan abalaye
PATAKI
ESIN LAWUJO YORUBA
Esin se
Pataki lawuojo Yoruba fun awon id wonyii
1. Esin je
ki a mo orirun ara eni
2. O n ko ni
ni iwa-bi-Olorun
3. O n ko ni
ni ilana akoso ti o to lawujo
4. O n se
atokun fun orin kiko, iji jjijo ati ewi kika
5. Esin je
amu ogbon fun awon onkawe, akotan ati akewi
6. O n se
okunfa irepo, ibagbepo,alaafia ati ibale okan
Comments
Post a Comment