KOKO EKO :
ERE IDARAYA
Ere idaraya ni ere ti tewe-tagba maa n se
leyin ise oojo won tabi ni akoko ti owo ba dile
Ere
idara wa fun takotabo, omode-tagba. Orisirisi ere idaraya ati isori ni o wa
1.) ERE OSUPA:
bojuboju, okun meran, eye meloo tonlogo waye
2.) ERE ABELE :
ayo olopon
3.) ERE ITA
GBANGBA : Arin, okoto , ijakadi, ere sisa, abbl
ERE
IDARAYA ODE ONI
1.) ERE ORI PAPA
: boolu afesegba ati afowogba, ere sisa, oniwon keke, ere asayi-papa-po , ere –
gbagi , olopo-ibuso, abbl
2.) ERE ABELE :
Dufaruti, kaadi, ludo .
ALEEBU
EDE IDARAYA
1.) Ijakadi le
je ki onkopa fi ara pa
2.) Elomiran le
daku
3.) Okoto tita
le da egbo si owo omo
4.) Iyepe le ta
si omo loju ni idi ere aarin tita
5.) Bojuboju le
je ki omo subu tabi ki o fese gun igi
ANFAANI
ERE IDARAYA
1.) O MAA MU KI
ARA OMODE JI PEPE
2.) Ayo tita maa
muni lo oju bi o ti ye
3.) Bojuboju maa
mu ki ara omode ya gaga
4.) O maa mu ewe
gbagbe ise oojo
5.) O wa fun
idaraya
6.) Ijakadi je
ona ti a fi n ko ni igboya ati agbara
Comments
Post a Comment