DIDEKUN IWA IKA SI OMOLAKEJI
Iwa ika ni iwa buburu,iwa ti ko dara ti omo eniyan n hu si omolakeji.
Orisi iwa ika ti o wopo ni aye atijo
1. Ikonileru
2. Ifinisofa
3. Fifi eniyan rubo
4. Gbigbe ese le iyawo oniyawo
5. Lile obinrin ni magun.
IWA IKA TI O WOPO LAYE ODE-ONI
1. Jijinigbe
2. Ipaniyan
3. Lilo omo ni ilokulo
4. Ifomosowo
5. Lilu iyawo ile
6. Ifapa bobirin lo
7. Biba omode ni asepo
8. Titan aarun kogbogun kale lona ti ko to
9. Lilu omo ni ilukulu
ONA TI A FI LE GBA DIN IWA IKA KU LAWUJO
1. Gbigba alaafia laye nigba gbogbo
2. Fifi ara eni si ipo enikeji ti a ba fe se ohun kan
3. Fifi agbofinro mu awon iseka lawujo
4. Fifi iya ti o to labe ofin je eni ti o ba huwa ika
5. Iwaasu oro Olorun ni awon ile ijosin
gbogbo
6. Tite agbalagba ti o ba ba omode ni ajosepo ni oda.
Comments
Post a Comment