ASAYAN EWI ALOHUN FUN ITUPALE
Ki a to so nipa ewi tabi litireso
alohun, a gbodo koko mo ohun ti ewi tabi litireso je.
Litireso/Ewi ni akojopo ijinle, ogbon
, asa ati ise Yoruba, o je ero okan tabi irir eni lori nnkan bii eniyan, ohun
elemi tabi alailemi ti a gbe kale lawujo lati ko ni logbon.
LITIRESO ni ise atinuda awon oloye lati
inu iriri ati akiyesi fun idanileko ati idanilaraya.
Litireso/ewi pin si ona meji :
1.
Litireso/ewi
alohun
2.
Litireso/ewi apileko
Litireso/ewi alohun: je ewi ajogunba ti a n fi ohun didun gbe jade lenu. Ona meta lo pin si
EWI ALOHUN
ITAN AJEMESIN AJEMAYEYE
|
Alo apamo |
Ijala |
Rara |
|
|
Esa/iwi |
Dadakuada |
|
Alo apagbe |
Oya pipe |
Biripo |
|
|
Sango pipe |
Ekun iyawo |
|
|
Esu pipe |
Adamo |
|
EWI ALOHUN |
AWON
TI WON N LO (AKOPA) |
|
Iyere Sisun |
Babalawo |
|
Iwi/Esa Egungun |
Oje/Elegun |
|
Esu Pipe |
Elesu |
|
Oya Pipe |
Oloya |
|
Ijala/ Iremoje |
Ode |
|
Arungbe |
Oloro |
|
Sango Pipe |
Onisango/Adosan |
Ti a ba fe se atupale asayan ewi
alohun, awon ohun ti a gbodo mo ni wonyii
1. Oriki ewi
alohun
2. Orisi ewi
alohun
3. Awon ohun ti
a le fid a ewi kookan mo. Apeere :- Ilu, Osere, Akoko isere, Akoonu, Abuda
adani.
4. Adugbo ti
okookan ti wo po. Gege bi apeere ewi alohun ajemayeye.
|
ISARE
FUN AYEYE |
ILU
TABI AGBEGBE |
|
Rara |
Oyo |
|
Etiyeri |
Oyo |
|
Ekun iyawo |
Oyo |
|
Bolojo |
Yewa (egbado ) |
|
Igbala |
Egba (Abeokuta) |
|
Ege /Ariwo/Orin agbe |
Egba |
|
Obitun |
Ondo |
|
Alamo |
Ekiti |
|
Dadakuada |
Igbomina /Ilorin |
|
Olele |
Ijesa |
|
Biripo |
Ikale |
|
Apepe |
Ijebu |
|
Agase |
Awori |
|
Adamo |
Ife |
5. Ilo-ede :- A
o ri orisirisi ona ewa ede ti won lo bi afiwe eleloo, afiwe taata, ifohunpeniyan,awitunwi,eyo
oro,olodindi gbolohun, apola gbolohun, abbl.

Comments
Post a Comment