AROKO
ATONISONA ALAPEJUWE
1. Eyi ni aroko
ti a fi n se apejuwe nnkan gege bi a se rii. A le se apejuwe ibikan, nnkan to
sele tabi eniyan. Bi apeere : -
2. Ile-iwe
mi
3. Anfin Oba
ilu mi
4. Oluko ede
Yoruba mi
5. Baba/iya
mi
6. Aja mi
7. Titi
Morose Eko si Ibadan
IGBESE
FUN AROKO KIKO
I.
Kiko ori oro:- A gbode ko ori-oro ti a yan, ki a si fa ile sii nidii
II.
Sise Ilepa Ero(guideline) : - eyi ni kiko ero wa sile, ki a so to won bo
se ye.
III.
Kiko Aroko:- Ifaara, aarin aroko ati ikaadii
IV.
Lilo ojulowo ede
Comments
Post a Comment