AROKO ALARINYANJINYAN
Eyi
ni irufe aroko ti o jemo iyan jije s'otun sosi. Ma ba b'ikanje ni aroko
alariyanjinyan. Iha meji ni o maa n ni. Akekoo si gbodo wo iha mejeji yii
finni-finni pelu koko to jiiree, ki o to wa fi ara mo iha ti o ba wu. Iha ti o ba faramo gbodo je eyi ti koko re po
julo.
Awon Apeere
Aroko Alariyanjiyan
1. Iyan se ara
lore ju eba lo
2. Omokunrin
dara ju omobinrin lo.
3. N je o to ki
a maa pa awon Adigun jale
4. N je o to ki
omobinrin maa wo aso okunrin
Comments
Post a Comment