Skip to main content

AMI OHUN JSS 2 (FIRST TERM )



 Kini ami ohun? Iro ohun ni iro aseyato  laarin oro meji tabi ju bee lo ti won ni sipeli kan naa sugbon  ti itumo won yato

               Orisii iro ohun meta ni o wa ninu ede Yoruba.

Awon ni

       I.          ohun oke ( ⁄ ) mi  high tone)

    II.          ohun aarin ( ) re (mid tone)

  III.          ohun isale (\ )do (low tone)

1.     ohun oke (m)( ⁄ ) ni ohun to lo soke lori iro

Bi apeere: -  wa- come, ji- wake up, ba – meet, wu- uproot

2.    2.  Ohun aarin (r) (.) ni- ohun ti yoo wa laarin ohun oke ati isale, kii ni ami lori iro

Bi apeere- rere- good, igi- tree, ire- good thing, ibi- bad thing


3.     Ohun isale (d) (\) ohun yoo waa sile lori iro faweeli

Bi apeere: - oke- up, aja- shelf, idi- Eagle.


    Ori oro- faweli ati iro konsonanti aranmupe ase silebu ‘’n’’ nikanni a n fi anai ohun le. Awon oro ti won re sipeli kan naa sugbon ti itumo won yato

Apeere

Igba – (time) d d

Igba- (calabash) r m

Igba- (garden egg) d m

 

Oko – (hoe) r m

Oko – (canoe) r d

Oko- (husband) r r

 

 

Owo- (money) r m

Owo- (Trade) d d

 

Ogun- (war) r r

Ogun- (inheritance) r m

Ogun- (medicine) d d

Comments

Popular posts from this blog

IHUN ORO/SILEBU JSS2 (SECOND TERM )

        SILEBU ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si wewe.         IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.      Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere: 1.Silebu/ihun oro  lee waye gege bi  faweli. O le je faweli airanmupe tabi faweli      aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un. 2.Silebu/ihun oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe .Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl. 3.Silebu/ihun oro  le waye bii konsonanti aranmu asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.                                    ...

AWON ORISA ILE YORUBA

ISORI EKO : AWON ORISA ILE YORUBA Awon Yoruba gba awon orisa bii asoju tabi iranse olodumare, alarina, lagata tabi alagbewi ni won je. Ero awon Yoruba ni pe olorun feran awon orisa wonyi.   Okanlenirinwo ni awon orisa ile Yoruba . lara won ni Obatala, Orunmila, Esu, Sango, Ogun ati bee bee lo   Obatala ni awon Yoruba pe ni ALAMORERE . Won gbagbo pe oun ni o mo gbogbo eya ara eniyan ki olodumare to mi emi iye si inu won Funfun   ni awon ohun elo obatala, lara won ni ileke funfun, aso funfun, bata funfun. Ounje ti o feran julo ni obe ate ( obe ti ko ni iyo ), igbin ati iyan. Omi ajipon ni obatala maa n mu. Ko feran iwa aito bi iro pipa ati ole- jija. Ko feran elede, epo, emu, iyo, aja tabi omi ikasi   Orunmila ( IFA) ni olodumare fun ni ogbon, imo ati oye lati tun aye se. won gba pe o wa nibe nigba ti olodumare n se ipin ede. Idi niyi ti won fi n pe ni   Eleri-pin   Sango ti a tun n pe ni OLUFIRAN ti je oba alaafin oyo ri. Won gb...

ATUNYEWO IPOLOWO OJA SSS2 (FIRST TERM)

  AKORI ISE : IPOLOWO OJA Ki awon eebo to de ni awon Yoruba ti n polowo oja,Ipolowo oja ni kikede ti a n kede oja ti a n ta fun awon eniyan ki won ba le mo ohun ti a n ta. ORISIIRISII ONA IPOLOWO OJA: (1) IPATE:Awon oloja le gbe oja sile ni oja, ikorita   ona oko tabi iwaju ile ni ori eni,tabili,kanta tabi kankere fun tita.Awon eleran osin le so eran won mo ori iso ,Ki aladiye ko adiye sinu ago ni oja lati ta.Eyi ni a n pen i ipate oja (2) IKIRI :Awon oloja maa n ru oja le ori kiri lati ta.Awon nnkan bee yoo je iwonba nnkan ti ko ni wuwo pupo .Awon alate oniworobo maa n kiri oja . (3) OGBON TI A FI N FA ONIBARA LOJU MORA Orisi ete ni awon ontaja maa n lo lati fa awon onibara mora ,ki won le so won di onibara titi kanri. (i)              ENI :Eyi nififi nnkan di si ori nnkan ti onibara ra bi ore.A le fi eni si eko tutu,iresi,gaari,epo abbl (ii)          ...