AKOTO EDE YORUBA
AKOTO EDE
YORUBA
Akoto ni
sipeli tuntun ti a fin ko ede Yoruba sile. Odunr 1974 ni awon igbimo ede Yoruba
fi owo sili lo won. Ona ti a fi le mo sipeli tuntun ni won yii.
i.
Ki a ya aworan ora kookan si okan wa.
ii.
Ki a maa ran won lenu tabi ko won sile nigba gbogbo.
iii.
Ki a maa se akiyesi won bi a ba n kawe.
Awon ofin to
de akoko atije niwonyii
Ofin 1 – Iro
faweli
Iro faweli
ko ye ninu awon oro bii – aiya, aiye, eiye ki a yo kuro
Akoto jo Akoto
tuntun
aiya aya
aiye aye
eiye eye
pepelye pepeye
eiyele eyele
yio yoo
enia eniyan
Ofin 2 –
Konsonanti meji papo ki ayo okan kuro
Otta Ota
Ebutte metta Ebute meta
Offa Ofa
Oshogbo Osogbo
Shagamu Sagamu
Ogboomosho Ogbomoso
Shaki Saki
Illa Ila
Ofin 3 – Iro
konsonanti ‘’n’’ inu oro bii nwon, eniyan, nyin, ko tona ki a yo kuro
nwon won
eniyin eyin
Nyin yin
tinyin tiyin
Ofin 4 – Ami
faagun – lilo ami faagun ni ori faweli inu oro bii – na, yi, olopa ko tona. Ami
lati ko won ni kikun bayii
Akoko atifo Akoko tuntun
(old smelling (New spelling)
tani ta ni
kini kin ni / ki ni
ewoni ewo ni
fihan fi han
jeki je ki
wipe wi pe
peki pe ki
gegebi gege bi
eniti eni ti
gbagbo gba gbo
eniti eni
ti
nitoripe nitori
pe
nitorina nitori
na
nigbati nigba ti
nigbagbogbo nigba gbogbo
niwongbati niwon gbati
lehinti lehin ti
biotilejepe bi o tileje pe
Ofin 6 –
Yiyan kuro ni ara oro ise
nlo n lo
nbo n bo
njeun n jeun
Comments
Post a Comment