AKAYE
Akaye ni ohun ti a ka ti o to yeni yekeyeke.
Ki a to le se aseyege ninu ayoka , a gbodo tele awon ofin wonyii.
1. A gbodo koko
sare ka ayoko naa daradara ki a mo koko oro inu e.
2. A gbodo ka
ibeere daadaa, ki a tun pada ka akaye wa lati fa idahun si ibeere yo
3. A gbodo lo
anfaani atunka yii lati mo agbegbe tabi ogangan ibi ti idahun si ibeere idahun
wa jade bi eni-ya-jigi.
Comments
Post a Comment