: AKANLO EDE ILE YORUBA
Akanlo
ede ni ipede ti o kun fun ijinle oro eyi
ti itumo re farasin. Akanlo ede je ona ti enyan n gba fi I pe oro so.
![]()
AKANLO –EDE (oro- oruko) ITUMO
Akoni,
akin Akinkanju eniyan
Eemo,
Kayeefi
Nnkan iyan
Gbewiri,
Olosa
Ole
Arowa
Ipe
![]()
AKANLO EDE (oro-ise) ITUMO
Fewo
Jale
Tiraka
Gbiyanju
Fariga,
Yari Binu
Omulemofo,
Pabu
Asan
![]()
APOLA ORO-ORUKO TABI APOLA ISE ITUMO
Je Olorun
nipe, Teri gbaso
KI eniyan ku
Gbana
je, Fi aake kori
Binu
Fi buredi ko
ni lobe je
Tan eniyan je
OKo Oba Ofin
Ijoba
AKANLO EDE ONIGBOLOHUN
![]()
AKANLO EDDE
ITUMO
Akara tu
sepo, Awo ya Asiri tu
Ese kan ile,
ese kan ode
Se iyemeji
Ikaa kan ko
wo o nidi
Ipa ko ka a
Eja n
bakan Bee
ni tabi bee ko
Ko iyan eni
kere
Fi oju kekere wo eniyan
Igi leyin
ogba Eni ti gbeke le
AKORI ISE – AKANLO EDE
Akanlo ede
je ona ti eniyan n gba pe oro so. Itumo Akanlo ede maa n farasin, o si maan le
je eleyo oro apola tabi odidi gbolohun.
|
Akanlo ede |
Itumo |
Ilo ninu gbolohun |
|
Akoni / Akin |
Akinkanju eni |
Akoni kan ki sojo loju ogun |
|
Eemo / Kayefi |
Nnkan Iyanu |
eemo wolu omo ole gba jo |
|
Arowa |
Ipe |
Oparo wa fun akekoo naa pe ki o lake ekun |
|
Otelemuye |
Olopaa Inu |
Awon otelemuye ti mu awon odaran naa |
|
Gbewiri / Olosa |
Ole |
Oganjo
oru ni awon olasa naa wo aarin ilu |
|
A nu ma daro |
Onirin
kunrin eniyan |
Irin anumadaro ti orin yii ko dun mo
mi ninu |
|
Fi oju oloore gungi di oloogbe / ta teru
nipe / Teri gbaso / gbemi mi |
ki eniyan ku |
|
|
Fi iru fo na |
fa oran / wahala |
So la lo
fi irufona pe lu omo ita |
|
Fi owo
leran |
Maa woye |
|
|
Reju |
Sun |
Baba n
reju lowo |
|
Napapa
bora |
Sa lo |
Awon odaran naa ti napapa bo ra |
|
Hawo |
ni ahun |
Tola hawo
ko le jeun senu ara re |
|
Nari /
fan ga |
Binu |
Awon lodo ilu fariga fun oba |
|
Gbaradi |
Mura |
Awon akekoo ti gbaradi fun idanwo |
|
Omulemofo / pabo |
Asan |
pabo ni / wadii awon olopaa naa jasi |
|
Nase |
Rin kiri |
Bola nase
lo si oja |
|
Fi aake
kori |
ko jale /
binu |
Baba oloko fi aake kori |

Comments
Post a Comment