SISE AGBEYEWO LITIRESO
APILEKO
Litireso
apileko ni awon iwe ewi, onitan aroso tabi ere onitan ti onkowe ko sile fun
kika, Pataki julo fun idanilekoo ati idanilaraya
IDI TI A FI
N KOWE LITIRESO APILEKO
1. Lati fid a
awon eniyan lara ya.
2. Lati fi ko
awon eniyan logbon
3. Lati yege
ninu idanwo
4. Lati mu ki
eniyan ronu ni ona ti o ye ko ro
5. Lati fi on
aero tun aidara ilu ati iwa omo araye se
6. Lati fi asa
ibile, iriri awon eniyan ati igbagbo won han.
Litireso apileko pin si ona meta:
I.
Ewi
II.
Itan
aroso
III.
Ere
onitan
ABUDA LITIRESO APILEKO
1.
Koko itan:- eyi ni ogbon atinuda ti onkowe lo lati hun itan re po di
odindin
2.
Ibudo itan :- eyin ni awon ibi kookan ti isele inu itan ti sele, O le je
adugbo tabi abule, inu igbo tabi eyin odi ilu.
3.
Eda itan ati Ifiwaweda :- eyi ni awon akopa inu itan, olu eda itan ni
ipo tire maa po ju.
4.
Ilo-ede:-itan aroso gbodo ni ede Yoruba to jiire bii owe, akonli ede,
afiwe, awitunwi, asodun, ifohunpeniyan,ifohundara,abbl.
5.
Asa :- Bii asa igbeyawo, Isomoloruko,Oye jije,abbl.
6.
Ibayemu:- se isele inu iwe ti a ka ba isele aye mu regi tabi bee ko. Eyi
ti o ba isele oju aye mu maa n dun un ka .
7.
Eko ti o ko ni.
8.
Ogbon isotan:- onkowe le lo ogbon arinurode, oju-mi-lose,Isoro-gbese ati
itan ninu itan
Comments
Post a Comment