Eyi ni sise ara eni losoo tabi sise ara loge. Iwa obun ni idakeji imototo. Awon Yoruba korira iwa obun pupo nitori pe o le fa aisan saye eni. ONA TI A LE GBA TOJU ARA ENI 1. Iwe wiwe 2. Enu fifo 3. Irun didi tabi gige 4. Eekanna gige 5. Aso fifo 6. Fifi adi agbon tabi ipara pa ara leyin iwe wiwe 7. Itoju ounje wa 8. Lilo ogun to ye : Ilokilo ogun ko dara ONA TI A GBA TOJU AYIKA WA 1. Gbigba ile ayika 2. Fifo ile iwe wa ati ile igbonse 3. Gige tabi riro oko ayika wa 4. Ile sisa kiri ayika ile wa 5. Dida ile nu si ibi ti o to 6. Yiye ona tori agbara ojo AWON OHUN ELO IMOTOTO Ose, Omi, Pako tabi Ifoyin, Kanin-kanin, Ipara,Igbale, Ada, Oko, abbl.