Skip to main content

OJO ATI OSU NI EDE YORUBA JSS1 (FIRST TERM)

 



OJO OSU ATI AKOKO (DAYS, MONTHS AND TIME)

 

OJO KOOKAN INU OSE


GEESI

YORUBA

ITUMO BI IGBAGBO YORUBA

Sunday

Aiku

The day of immortality

Monday

Aje

The day of financial

Tuesday

Isegun

The day of victory

Wednesday

Ojoru

The day of confusion

 

Thursday

 

Ojobo

The  day of the new creation

 

Friday

 

Eti

The of unsuccessful attempt

 

Saturday

 

Abameta

The day of three resolution

 

OSU INU ODUN

GEESI

OSU NI SISE- N- TELE

BI YORUBA SE PE WON

January

Osu kin- in- ni

Sere

Febuary

Osu keji

Erele

March

Osu keta

Erena

April

Osu kerin

Igbe

May

Osu karun-un

Ebibi

June

Osu kefa

Okudu

July

Osu keje

Agemo

August

Osu kejo

Ogun

September

Osu kesan- un

Owewe

October

Osu kewaa

Owara

November

Osu kokawa

Belu

December

Osu keji la

Ope

 

ASIKO/ AKOKO

ASIKO

YORUBA

NI GBOLOHUN

5: 00 am- 12:00 pm

aaro

mo ri oni aaro (laaro)

12. noon- 3.30pm

osan

wari mi ni osan (losan)

7.00pm- 11.59pm

ale

Ni ale (lale) ana ni mode

12 midnight- 4.30am

Oru

irin oru ko ye omo eniyan

Now

isisiyi

Ni isiyi ni mo fe lo

Yesterday

ana

ana ni mo san owo naa

Today

oni

oni gan- an ni ipade wa

Tomorrow

Ola

je ki a ri ra ni ola

Three days ago

Ijeta

jeta ni mo pada wale

Next week

Ose to n bo

ose ton bo ni ki o wa

Last week

Ose to ko ja

Ose to koja ni a pari ise wa

Comments

Popular posts from this blog

IHUN ORO/SILEBU JSS2 (SECOND TERM )

        SILEBU ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si wewe.         IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.      Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere: 1.Silebu/ihun oro  lee waye gege bi  faweli. O le je faweli airanmupe tabi faweli      aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un. 2.Silebu/ihun oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe .Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl. 3.Silebu/ihun oro  le waye bii konsonanti aranmu asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.                                    ...

AWON ORISA ILE YORUBA

ISORI EKO : AWON ORISA ILE YORUBA Awon Yoruba gba awon orisa bii asoju tabi iranse olodumare, alarina, lagata tabi alagbewi ni won je. Ero awon Yoruba ni pe olorun feran awon orisa wonyi.   Okanlenirinwo ni awon orisa ile Yoruba . lara won ni Obatala, Orunmila, Esu, Sango, Ogun ati bee bee lo   Obatala ni awon Yoruba pe ni ALAMORERE . Won gbagbo pe oun ni o mo gbogbo eya ara eniyan ki olodumare to mi emi iye si inu won Funfun   ni awon ohun elo obatala, lara won ni ileke funfun, aso funfun, bata funfun. Ounje ti o feran julo ni obe ate ( obe ti ko ni iyo ), igbin ati iyan. Omi ajipon ni obatala maa n mu. Ko feran iwa aito bi iro pipa ati ole- jija. Ko feran elede, epo, emu, iyo, aja tabi omi ikasi   Orunmila ( IFA) ni olodumare fun ni ogbon, imo ati oye lati tun aye se. won gba pe o wa nibe nigba ti olodumare n se ipin ede. Idi niyi ti won fi n pe ni   Eleri-pin   Sango ti a tun n pe ni OLUFIRAN ti je oba alaafin oyo ri. Won gb...

AWE GBOLOHUN (JSS)

 AWE GBOLOHUN   AWE GBOLOHUN ni ipede to ni oluwa ati ohun ti oluwa n se . ona meji Pataki ni awe gbolohun pin si . Olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe, Olori awe gbolohun maa n da duro, yoo si ni itumo, o si maa n sise gbolohun abode. Apeere   1) Ola ti sun                2) Mo n bo   Awe gbolohun afarahe tabi afibo : eyi ni gbolohun ti ko le da duro ko si fun wa ni itumo, o maa darale olori gbolohun ni, o si maa n wonpo ninu gbolohun olopo oro ise ( onibo )   Lara awon atoka gbolohun afarahe ni : ti, pe, ki, iba, bi, boya, tabi ati bee bee lo. Awe gbolohun le wa ni   ibeere, aarin tabi ipari gbolohun. Isori meta ni a le pin si. Awon si ni : 1.     ASODORUKO 2.     ASAPEJUWE 3.     ASAPONLE AWE GBOLOHUN ASODORUKO : eyi ni odidi gbolohun ti a so di oro-oruko nipa lilo oro atoka   “PE” Apeere   : ...