Skip to main content

Posts

Showing posts from April, 2021

AYAN OGBUFO SSS1 (SECOND TERM)

  AayanOgbufo. Ayan ogbufo ni sise itumo ede kan si omiran. Ise ogbufo kuro ni   gbefe, o gba ki a ni imo lori ede mejeji, itumo awon ona ede bi owe ati akanlo ede inu ede ti a fe tumo ati ede ti a fe tumo re si . Ede Yoruba atata ati ilo amin ohun se Pataki ninu ise ogbufo alakoole. AAYAN OGBUFO ELEYO ORO Abandon                                    ko sile Abstain                                       Fa seyin Compare                                     Fiwe Deceit                                         Etan Education                                 Imo-eko Entertainment                         Idaraya Home work                             Ise asetilewa Overlap                                    Wonu ara Research                                  Iwadi Transfer                                     Isinipo   Joke                                         Apara Wonder                                  Iyanu   AAYAN OGBUFO ONIGBOLOHUN OWE ATI AKANLO EDE

ASA ISINKU SSS2 (SECOND TERM)

  ASA ISINKU Iranse Olodumare ni awon Yoruba ka iku si. Iku kii gba riba tabi ebe, gbese ni iku, ko si eni ti ko ni san. Irin ajo si orun ni Yoruba ka iku si. Asa isinku ni eto ikeyin ti a n se fun oku. Awon orisirisi iku ti si n pani ni wonyii : Aisan, Ijanba lorisirisi, Iku aitojo, Fifowororiku. ETO ISINKU Eyi   ni eto isinku agbalagba ti o fi owo rori ku. 1.       IPALEMO ILE ATI OKU: bi oku ba ti ku, kii a to pariwo sita, a gbodo tun gbogbo ile se daadaa, ki a gbe oku si ori eni ti o dara. 2.      ITUFO : eyi ni ikede iku fun ebi ati aladugbo, ekun ni eni ti o ko ri oku yoo fi tufo fun awon ara ile. Bi oku ba se je ni a n tufo re. ti o ba je Oba a kii n so pe oba ku, oba waja ni won maa n so. Ti oba ba waja, won yoo koko se etutu, ki awon agbagba tabi ijoye ilu to tufo re. 3.      ITOJU OKU : won yoo we e mo pelu koinkion ati ose ni ehinkule. Okunrin ni we oku okunrin, ti obinrin si n we oku obinrin. Ti o ba je okunrin, won yoo wo ni ewu,sokoto ati fila, won yoo si f

ATUNYEWO IPOLOWO OJA SSS2 (FIRST TERM)

  AKORI ISE : IPOLOWO OJA Ki awon eebo to de ni awon Yoruba ti n polowo oja,Ipolowo oja ni kikede ti a n kede oja ti a n ta fun awon eniyan ki won ba le mo ohun ti a n ta. ORISIIRISII ONA IPOLOWO OJA: (1) IPATE:Awon oloja le gbe oja sile ni oja, ikorita   ona oko tabi iwaju ile ni ori eni,tabili,kanta tabi kankere fun tita.Awon eleran osin le so eran won mo ori iso ,Ki aladiye ko adiye sinu ago ni oja lati ta.Eyi ni a n pen i ipate oja (2) IKIRI :Awon oloja maa n ru oja le ori kiri lati ta.Awon nnkan bee yoo je iwonba nnkan ti ko ni wuwo pupo .Awon alate oniworobo maa n kiri oja . (3) OGBON TI A FI N FA ONIBARA LOJU MORA Orisi ete ni awon ontaja maa n lo lati fa awon onibara mora ,ki won le so won di onibara titi kanri. (i)              ENI :Eyi nififi nnkan di si ori nnkan ti onibara ra bi ore.A le fi eni si eko tutu,iresi,gaari,epo abbl (ii)            ITO,:WO :Yoruba ni itowo ni adun obe”Eyi ni ki onibara to die wo ninu ohun ti o f era.Awon nnkan ti a le towo ni g